Monday, April 13, 2009

IROYIN IPINLE

1 comment:

 1. ATUNDI ETO IDIBO EKITI,ADELE AGBENUSO NI OHUN O MO AWON ODARAN RI, O PE FUN IWADI TI O TO.
  Adele Agbenuso Ipinle Ekiti, Ogbeni Saliu Adeoti, ti ke gbajare ni Ojo Aiku, lanaa ti pe Komisona olopaa ipinle naa, Ogbeni Chris Ola lati fi oju awon ti o wa latimole lori oro atundi ibo ijoba han.
  O ni ohun ko mo awon marun ti won mu ni ojo Abameta pelu awon ohun ija oloro ni Igbara-Odo ti won ni won san owo fun won lati daabo bo ijoba ri, ni igba ti o m ba awon oniroyin soro ni Otun-Ekiti.
  O ni lesekese ti ohun ti gbo oro pe won tu asiri naa ni ohun ti kan si Asoju gomina, Ogbeni Tunji Odeyemi, ti ohun naa si ni ohun ko mo nipa re.
  O ni Ile Igbimo Asofin ohun pelu ijoba ko pe fun aabo lodo enikan kan olopaa tabi awon moba nigba ti ko si wahala ti o sele.
  Adeoti wa ni awon eeyan marun ti won mu pelu awon ohun ija oloro naa ko ba ti se ipalara fun awon ara ilu ti ko mo ka ni awon olopaa ko ri won mu.

  ReplyDelete